Ísíkẹ́lì 1:7 BMY

7 Ẹsẹ̀ wọn sì tọ́; àtẹ́lẹsẹ̀ wọn sì rí bí ti ọmọ màlúù, wọ́n sì tàn bí awọ idẹ dídán.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 1

Wo Ísíkẹ́lì 1:7 ni o tọ