Ísíkẹ́lì 10:7 BMY

7 Ọ̀kan nínú àwọn kérúbù sì nawọ́ síbi iná tó wà láàrin kérúbù yóòkù. Ó mú lára rẹ, ó fi sínú ọwọ́ ọkùnrin aláṣọ funfun, òun náà gbàá, ó sì jáde lọ.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 10

Wo Ísíkẹ́lì 10:7 ni o tọ