Ísíkẹ́lì 11:12 BMY

12 Ẹ̀yin ó sì mọ̀ pé Èmi ni Olúwa, nítorí pé ẹ̀yin kò tẹ̀lé àṣẹ mi ẹ kò sì pa òfin mi mọ́, ṣùgbọ́n ẹ ti hùwà gẹ́gẹ́ bí àwọn aláìgbàgbọ́ orílẹ̀ èdè tó yí yín ká.”

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 11

Wo Ísíkẹ́lì 11:12 ni o tọ