Ísíkẹ́lì 11:2 BMY

2 Olúwa sì sọ fún mi pé, “Ọmọ ènìyàn, àwọn ọkùnrin yìí ló ń pète ibi, wọ́n sì ń gba ìmọ̀ràn búburú kalẹ̀ nínú ìlú.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 11

Wo Ísíkẹ́lì 11:2 ni o tọ