Ísíkẹ́lì 11:7 BMY

7 “Torí náà, báyìí ni Olúwa Ọlọ́run wí, àwọn òkú tí ẹ pa sáàrin yín ni ẹran, ìlú yìí sì ni ìkòkò ìdáná ṣùgbọ́n n ó le yín jáde níbẹ̀.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 11

Wo Ísíkẹ́lì 11:7 ni o tọ