Ísíkẹ́lì 12:12 BMY

12 “Ọmọ aládé tó wà láàrin wọn yóò di ẹrù rẹ lé èjìká lálẹ́ yóò sì jáde lọ, òun náà yóò da ògiri lu kí ó le gba ibẹ̀ jáde. Yóò sì bo ojú rẹ̀ kí ó má ba à rí ilẹ̀.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 12

Wo Ísíkẹ́lì 12:12 ni o tọ