Ísíkẹ́lì 12:22 BMY

22 “Ọmọ ènìyàn, irú òwé wo lẹ ń pa nílẹ̀ Ísírẹ́lì pé: ‘A fa ọjọ́ gùn, gbogbo ìran di asán’?

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 12

Wo Ísíkẹ́lì 12:22 ni o tọ