Ísíkẹ́lì 12:4 BMY

4 Di ẹrù ìgbèkùn rẹ lójú wọn lọ́sàn án gangan, nígbà tó bá sì di alẹ́, loju wọn máa lọ sí ìgbèkùn gẹ́gẹ́ bí àwọn tí ó lọ ìgbèkùn ṣe máa ń ṣe.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 12

Wo Ísíkẹ́lì 12:4 ni o tọ