Ísíkẹ́lì 13:21 BMY

21 Èmi yóò ya àwọn ìbòjú yín, láti gba àwọn ènìyàn mi lọ́wọ́ yín, wọn kò sì ní jẹ́ ìjẹ fún yín mọ́. Nígbà náà ni ẹ ó mọ̀ pé Èmi ni Olúwa.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 13

Wo Ísíkẹ́lì 13:21 ni o tọ