Ísíkẹ́lì 13:5 BMY

5 Ẹ kò gòkè láti mọ odi tí ó ya ní ilẹ̀ Ísírẹ́lì kí wọ́n ba lè dúró gbọin lójú ogun lọ́jọ́ Olúwa.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 13

Wo Ísíkẹ́lì 13:5 ni o tọ