Ísíkẹ́lì 14:13 BMY

13 “Ọmọ ènìyàn bí orílẹ̀ èdè kan bá ṣẹ́ mí nípa ìwà àìṣòdodo, èmi yóò nawọ́ mi jáde sí wọn, láti gé ìpèsè oúnjẹ wọn, n ó rán ìyàn sí wọn, èmi yóò sì pa ènìyàn àti ẹranko inú rẹ̀,

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 14

Wo Ísíkẹ́lì 14:13 ni o tọ