Ísíkẹ́lì 14:17 BMY

17 “Tàbí tí mo bá mú idà kọjá láàrin orílẹ̀ èdè náà tí mo wí pé, ‘Ẹ jẹ́ kí idà kọjá láàrin ilẹ̀ náà,’ tí mo sì tú ìbínú gbígbóná lé wọn lórí nípa ìtàjẹ́sílẹ̀, tí mo pa ènìyàn àti ẹranko inú rẹ.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 14

Wo Ísíkẹ́lì 14:17 ni o tọ