Ísíkẹ́lì 15:6 BMY

6 “Nítorí náà, báyìí ni Olúwa Ọlọ́run wí: Bí mo ṣe sọ igi àjàrà tó wà láàrin àwọn igi inú igbó yóòkù di igi ìdáná, bẹ́ẹ̀ ni Èmi yóò ṣe ṣe gbogbo ènìyàn tó ń gbé Jérúsálẹ́mù.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 15

Wo Ísíkẹ́lì 15:6 ni o tọ