Ísíkẹ́lì 16:10 BMY

10 Mo fi aṣọ oníṣẹ́ ọ̀nà sí ọ lára láti wọ̀ ọ́, mo wọ bàtà aláwọ fún ọ. Mo fi aṣọ funfun lẹlẹ àti aṣọ olówó iyebíye ṣe ọ́ lọ́ṣọ̀ọ́.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 16

Wo Ísíkẹ́lì 16:10 ni o tọ