Ísíkẹ́lì 16:22 BMY

22 Nínú gbogbo iṣẹ́ ìríra àti ìwà àgbérè rẹ, o kò rántí ìgbà èwe rẹ, nígbà tó o wà ní ìhòòhò, tó ń jàgùdù nínú ẹ̀jẹ̀.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 16

Wo Ísíkẹ́lì 16:22 ni o tọ