Ísíkẹ́lì 16:3 BMY

3 Sọ pé, ‘Báyìí ni Olúwa Ọlọ́run wí sí Jérúsálẹ́mù: Ìran rẹ àti ilẹ̀ ìbí rẹ wà ní ilẹ̀ Kénáànì; ará Ámórì ni baba rẹ̀, ìyá rẹ̀ sì jẹ́ ará Hítì.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 16

Wo Ísíkẹ́lì 16:3 ni o tọ