Ísíkẹ́lì 16:33 BMY

33 Àwọn ọkùnrin máa ń sanwó fún àwọn aṣẹwó ni ṣùgbọ́n ìwọ lo tún ń sanwó fun wọn, tí ó tún ń fún àwọn olólùfẹ́ rẹ lẹ́bùn àti owó ẹ̀yìn kí wọn bá à le máa wá ọ wá láti gbogbo agbègbè fún àgbèrè ṣíṣe.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 16

Wo Ísíkẹ́lì 16:33 ni o tọ