Ísíkẹ́lì 16:42 BMY

42 Nígbà náà ni ìbínú mi sí Ọ yóò rọ̀, owú ìbínú mi yóò sì kúrò lọ́dọ̀ rẹ; inú mi yóò rọ, èmi kò sì ní bínú mọ́.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 16

Wo Ísíkẹ́lì 16:42 ni o tọ