Ísíkẹ́lì 16:49 BMY

49 “ ‘Wò ó, ẹ̀sẹ̀ tí Sódómù ẹ̀gbọ́n rẹ̀ obìnrin sẹ̀ nìyìí: Òun àti àwọn ọmọbìnrin rẹ gbéraga, wọ́n jẹ́ alájẹjù àti aláìbìkítà; wọn kò ran talákà àti aláìní lọ́wọ́

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 16

Wo Ísíkẹ́lì 16:49 ni o tọ