Ísíkẹ́lì 16:51 BMY

51 Samaríà kò ṣe ìdájìn ẹ̀ṣẹ̀ rẹ. Ìwọ ṣe àwọn ohun ìríra ju tirẹ̀ lọ, ìwọ sì jẹ kí àwọn arabìnrin rẹ dàbí olódodo pẹ̀lú gbogbo ìwọ̀nyí tí ìwọ ti ṣe.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 16

Wo Ísíkẹ́lì 16:51 ni o tọ