Ísíkẹ́lì 16:55 BMY

55 Nígbà tí àwọn arábìnrin rẹ, Sódómù àti àwọn ọmọbìnrin rẹ; Samaríà àti àwọn ọmọbìnrin rẹ ba padà si ipò tí wọn wà tẹ́lẹ̀, ìgbà náà ni ìwọ náà yóò padà sí ipò àtijọ́ rẹ.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 16

Wo Ísíkẹ́lì 16:55 ni o tọ