Ísíkẹ́lì 16:63 BMY

63 Nígbà tí mo bá sì ti ṣe ètùtù fún gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ rẹ tan, Èmi yóò sì rántí ojú yóò tì ọ́, ìwọ kò sì ní le ya ẹnu rẹ mọ́ nítorí ìtìjú rẹ, ni Olúwa Ọlọ́run wí.’ ”

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 16

Wo Ísíkẹ́lì 16:63 ni o tọ