Ísíkẹ́lì 17:10 BMY

10 Bí a tilẹ̀ tún un gbìn, yóò wa gbilẹ̀ bí? Kò wá ní i rọ pátapáta nígbà ti afẹ́fẹ́ láti ìlà oòrùn bá kọ lù ú. Gbogbo ewé rẹ̀ yóò rẹ̀ lórí ilẹ̀ tó ti dàgbà?’ ”

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 17

Wo Ísíkẹ́lì 17:10 ni o tọ