Ísíkẹ́lì 17:18 BMY

18 Nítorí pé ó kẹ́gàn ẹ̀jẹ́ nípa dída májẹ̀mú, àti pé ó juwọ́ sílẹ̀ nínú ṣíṣe ìlérí, kò ní i bọ níbẹ̀ pẹ̀lú gbogbo àwọn nǹkan to ṣe yìí.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 17

Wo Ísíkẹ́lì 17:18 ni o tọ