Ísíkẹ́lì 17:21 BMY

21 Gbogbo ìsáǹsá àti ọ̀wọ́ ọmọ ogun rẹ̀ ni yóò kú pẹ̀lú idà, èmi yóò sì fọn àwọn ìyókù ká sínú afẹ́fẹ́ káàkiri. Nígbà náà ni yóò mọ̀ pé, “Èmi Olúwa lo sọ̀rọ̀.”

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 17

Wo Ísíkẹ́lì 17:21 ni o tọ