Ísíkẹ́lì 18:2 BMY

2 “Kín ni ẹ̀yín rò tí ẹ̀yin fi ń pa òwe nípa Ísírẹ́lì wí pé:“ ‘Àwọn baba ti jẹ èso àjàrà kíkan,eyín àwọn ọmọ sì kan.’

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 18

Wo Ísíkẹ́lì 18:2 ni o tọ