Ísíkẹ́lì 18:29 BMY

29 Síbẹ̀, ilé Ísírẹ́lì wí pé, ‘Ọ̀nà Olúwa kò tọ́.’ Ọ̀nà mi kò ha tọ́ bí Ilé Ísírẹ́lì? Kì í wa se pè ọ̀nà tiyín gan an ni ko tọ?

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 18

Wo Ísíkẹ́lì 18:29 ni o tọ