11 Àwọn ẹ̀ka rẹ̀ lágbára tó láti fi ṣe ọ̀pá àṣẹ ìjòyè,ó ga sókè láàrin ewé rẹ̀,gíga rẹ̀ hàn jáde láàrin ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀ka rẹ̀.
Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 19
Wo Ísíkẹ́lì 19:11 ni o tọ