9 Wọn fi ìkọ́ gbé e sínú ago, wọn mú un lọ sí ọ̀dọ̀ Ọba Bábílónì,wọn fi sínú ìhámọ́, a kò sì gbọ́ bíbú rẹ̀ mọ́ lórí òkè Ísírẹ́lì.
Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 19
Wo Ísíkẹ́lì 19:9 ni o tọ