Ísíkẹ́lì 2:1 BMY

1 Ó sọ fún mi pé, “Ọmọ ènìyàn, dìde dúró lórí ẹṣẹ̀ rẹ. Èmi yóò bá ọ sọ̀rọ̀.”

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 2

Wo Ísíkẹ́lì 2:1 ni o tọ