Ísíkẹ́lì 2:8 BMY

8 Ṣùgbọ́n ìwọ, ọmọ ènìyàn, gbọ́ ohun tí mo ń sọ fún ọ. Má se ṣọ̀tẹ̀ bí i ti ìdílé ọlọ́tẹ̀; la ẹnu rẹ kí o sì jẹ ohun tí mo fún ọ.”

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 2

Wo Ísíkẹ́lì 2:8 ni o tọ