Ísíkẹ́lì 20:10 BMY

10 Nítorí náà, mo mú wọn jáde ní ilẹ̀ Éjíbítì mo sì mú wọn wá sínú ihà.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 20

Wo Ísíkẹ́lì 20:10 ni o tọ