Ísíkẹ́lì 20:12 BMY

12 Bẹ́ẹ̀ ni mo fún wọn ní ọjọ́ ìsinmi gẹ́gẹ́ bí àmì láàrin àwọn àti èmi, kí wọn lè mọ̀ pé èmi ni Olúwa tó sọ wọn di mímọ́.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 20

Wo Ísíkẹ́lì 20:12 ni o tọ