Ísíkẹ́lì 20:16 BMY

16 Nítorí pé wọn kọ òfin mi sílẹ̀, wọn kò sì tẹ̀lé àsẹ mi, wọn sọ ọjọ́ ìsinmi mi dí aláìmọ́. Nítorí pé tọkàntọkàn ni wọn ń tẹ̀lé òrìṣà wọn.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 20

Wo Ísíkẹ́lì 20:16 ni o tọ