Ísíkẹ́lì 20:43 BMY

43 Níbẹ̀ ni ẹ ó wa rántí ìwà àti gbogbo ìsesí yín, èyí tí ẹ̀yin fi sọ ara yín di aláìmọ́, ẹ̀yin yóò sì kóríra ara yín fún gbogbo ibi tí ẹ̀yin ti se.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 20

Wo Ísíkẹ́lì 20:43 ni o tọ