29 Bí ó tilẹ jẹ́ pé a rì èké nípa yínàti àfọ̀sẹ èké nípa yína yóò gbé e lé àwọn ọrùnènìyàn búburú ti a yóò pa,àwọn tí ọjọ́ wọn ti dé,àwọn tí ọjọ́ ìjìyà wọn ti dé góńgó.
30 Dá idà padà sínú akọ rẹ̀Níbi tí a gbé sẹ̀dá yín,ní ibi tí ẹ̀yin ti sẹ̀ wá.
31 Níbẹ̀ ni èmi yóò ti ṣe ìdájọ́ yín,èmi yóò sì fi èémí ìbínú gbígbónámi bá yín jà.
32 Ẹ̀yin yóò jẹ́ èpò fún iná náà,a yóò ta ẹ̀jẹ̀ yin sórí ilẹ̀ yín,a ki yóò rántí yín mọ́;nitorí èmi Olúwa ní ó ti wí bẹ́ẹ̀.’ ”