Ísíkẹ́lì 21:4 BMY

4 Nítorí pé, èmi yóò ké olódodo àti olùṣe búburú kúrò, idà mi yóò jáde láti inú àkọ̀ rẹ̀ lòdì sí gbogbo ènìyàn láti gúsù títí dé àríwá.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 21

Wo Ísíkẹ́lì 21:4 ni o tọ