Ísíkẹ́lì 22:11 BMY

11 Nínú rẹ ọkùnrin kan ti dá ẹ̀ṣẹ̀ ìríra pẹ̀lú aya aládùúgbò rẹ̀, òmíràn bá ìyàwó ọmọ rẹ̀ ṣe, òmíràn sì bá arábìnrin rẹ̀ lòpọ̀ èyí tí í ṣe ọbàkan rẹ̀.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 22

Wo Ísíkẹ́lì 22:11 ni o tọ