Ísíkẹ́lì 22:13 BMY

13 “ ‘Èmi yóò kúkú pàtẹ́wọ́ lórí èrè àìmọ̀ tí ìwọ ti jẹ, àti lórí ẹ̀jẹ̀ tí ìwọ ti ta sílẹ̀ ní àárin yín.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 22

Wo Ísíkẹ́lì 22:13 ni o tọ