Ísíkẹ́lì 22:7 BMY

7 Nínú rẹ wọn ti hùwà sí baba àti ìyá pẹ̀lú ìfojú tínrín; nínú rẹ wọn ti ni àwọn àlejò lára, wọn sì hùwà-kúwà sí aláìní baba àti opó.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 22

Wo Ísíkẹ́lì 22:7 ni o tọ