Ísíkẹ́lì 23:15 BMY

15 pẹ̀lú ìgbànú ni ìdí wọn àti àwọn ìgbàrí ni orí wọn; gbogbo wọn dàbí olórí kẹ̀kẹ́ ogun Bábílónì ọmọ ìlú Kálídíà.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 23

Wo Ísíkẹ́lì 23:15 ni o tọ