Ísíkẹ́lì 23:20 BMY

20 Níbẹ̀ ni ó ti ṣe ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ sí àwọn olólùfẹ́ rẹ̀, tí àwọn tí ǹnkan ọkùnrin wọn dàbí ti kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́, àwọn ẹni tí ìtíjáde ara wọn dàbí ti àwọn ẹṣin.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 23

Wo Ísíkẹ́lì 23:20 ni o tọ