Ísíkẹ́lì 23:22 BMY

22 “Nítorí náà, Óhólíbà, báyìí ní Olúwa Olódùmarè wí: Èmi yóò gbé olólùfẹ́ rẹ dìde sí ọ, àwọn tí o kẹ́yìn si ní ìtìjú, èmi yóò sì mú wọn dojú kọ ọ́ ní gbogbo ọ̀nà

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 23

Wo Ísíkẹ́lì 23:22 ni o tọ