Ísíkẹ́lì 23:32 BMY

32 “Èyí yìí ní Olúwa Olódùmarè:“Ìwọ yóò mu nínú aago ẹ̀gbọ́n rẹ,aago tí ó tóbi tí ó sì jinnú:yóò mú ìfisẹ̀sín àti ìfiṣe ẹlẹ́yà wá,nítorí tí aago náà gba nǹkan púpọ̀.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 23

Wo Ísíkẹ́lì 23:32 ni o tọ