Ísíkẹ́lì 23:40 BMY

40 “Wọn tilẹ̀ rán oníṣẹ́ sí àwọn ènìyàn tí wọ́n wá láti ọ̀nà jíjìn, nígbà tí wọ́n dé, ìwọ wẹ ara rẹ fún wọn, ìwọ kún ojú rẹ, ìwọ sì fi ọ̀sọ́ iyebíye sára,

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 23

Wo Ísíkẹ́lì 23:40 ni o tọ