27 Ní ọjọ́ náà ẹnu rẹ yóò sì sí; ìwọ yóò sọ̀rọ̀, ìwọ kì yóò sì yadi mọ́. Báyìí ìwọ yóò jẹ́ àmì fún wọn; wọn yóò sì mọ̀ pé èmi ní Olúwa.”
Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 24
Wo Ísíkẹ́lì 24:27 ni o tọ