Ísíkẹ́lì 26:4 BMY

4 Wọn yóò wó odi Tírè lulẹ̀, wọn yóò sì wo ilé ìṣọ́ rẹ̀ lulẹ̀; Èmi yóò sì ha ẹrùpẹ̀ rẹ̀ kúrò, Èmi yóò sì sọ ọ́ di orí àpáta.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 26

Wo Ísíkẹ́lì 26:4 ni o tọ