Ísíkẹ́lì 27:15 BMY

15 “ ‘Àwọn ènìyàn Ródísì ni àwọn oníṣòwò rẹ, àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ erékùṣù ni wọ́n jẹ́ onibárà rẹ̀; wọ́n mú eyín-erin àti igi ébónì san owó rẹ.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 27

Wo Ísíkẹ́lì 27:15 ni o tọ