Ísíkẹ́lì 27:17 BMY

17 “ ‘Júdà àti Ísírẹ́lì, àwọn ni oníṣòwò rẹ; wọn ṣe ìpààrọ̀ ọkà, Mínnítì, àkàrà àdídùn; pannági, oyin, epo àti ìpara olóòórùn dídùn ni wọ́n fi ná ọjà rẹ.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 27

Wo Ísíkẹ́lì 27:17 ni o tọ