Ísíkẹ́lì 27:3 BMY

3 Sọ fún Tírè, tí a tẹ̀dó sí ẹnu bodè òkun, oníṣòwò àwọn orílẹ̀-èdè fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ erékùṣù. ‘Èyí yìí ní Olúwa Ọlọ́run wí:“ ‘Ìwọ Tírè wí pé“Ẹwá mi pé.”

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 27

Wo Ísíkẹ́lì 27:3 ni o tọ